Yoruba

Christus Cabrini Surgery Center tẹle ilana ofin ijọba apapọ lori etọ arailu ati pe wọn ko gbọdọ sojuṣaaju lori ọrọ ẹya, àwo, ilu-abinibi, ọjọ-ori, abarapa tabi jijẹ ọkunrin tabi obinrin.

AKIYESI: Bi o ba nsọ èdè Yorùbú ọfé ni iranlọwọ lori èdè wa fun yin o. Ẹ pe ẹrọ-ibanisọrọ yi (318) 427-6500.